Ìsíkíẹ́lì 20:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Àmọ́ èmi yóò mú àwọn ọlọ̀tẹ̀ àti àwọn tó ń ṣẹ̀ mí kúrò láàárín yín.+ Màá mú wọn kúrò ní ilẹ̀ àjèjì tí wọ́n wà, àmọ́ wọn ò ní wọ ilẹ̀ Ísírẹ́lì;+ ẹ ó sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.’
38 Àmọ́ èmi yóò mú àwọn ọlọ̀tẹ̀ àti àwọn tó ń ṣẹ̀ mí kúrò láàárín yín.+ Màá mú wọn kúrò ní ilẹ̀ àjèjì tí wọ́n wà, àmọ́ wọn ò ní wọ ilẹ̀ Ísírẹ́lì;+ ẹ ó sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.’