-
Míkà 5:13, 14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Màá run àwọn ère gbígbẹ́ àti àwọn ọwọ̀n yín kúrò láàárín yín,
Ẹ kò sì ní forí balẹ̀ fún iṣẹ́ ọwọ́ yín mọ́.+