Sáàmù 81:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Èmi, Jèhófà, ni Ọlọ́run rẹ,Ẹni tó mú ọ jáde kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ La gbogbo ẹnu rẹ, màá sì fi oúnjẹ kún un.+ 11 Àmọ́ àwọn èèyàn mi ò fetí sí ohùn mi;Ísírẹ́lì kò ṣègbọràn sí mi.+
10 Èmi, Jèhófà, ni Ọlọ́run rẹ,Ẹni tó mú ọ jáde kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ La gbogbo ẹnu rẹ, màá sì fi oúnjẹ kún un.+ 11 Àmọ́ àwọn èèyàn mi ò fetí sí ohùn mi;Ísírẹ́lì kò ṣègbọràn sí mi.+