Àìsáyà 28:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nítorí ẹ sọ pé: “A ti bá Ikú dá májẹ̀mú,+A sì ti bá Isà Òkú* ṣe àdéhùn.* Tí omi tó ń ru gùdù bá ya kọjá lójijì,Kò ní dé ọ̀dọ̀ wa,Torí a ti fi irọ́ ṣe ibi ààbò wa,A sì ti fi ara wa pa mọ́ sínú èké.”+
15 Nítorí ẹ sọ pé: “A ti bá Ikú dá májẹ̀mú,+A sì ti bá Isà Òkú* ṣe àdéhùn.* Tí omi tó ń ru gùdù bá ya kọjá lójijì,Kò ní dé ọ̀dọ̀ wa,Torí a ti fi irọ́ ṣe ibi ààbò wa,A sì ti fi ara wa pa mọ́ sínú èké.”+