Àìsáyà 10:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àní, ìparun ráúráú tí Olúwa Ọba Aláṣẹ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun pinnu,Máa ṣẹlẹ̀ ní gbogbo ilẹ̀ náà.+ Àìsáyà 24:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Wò ó! Jèhófà máa sọ ilẹ̀ náà* di òfìfo, ó sì máa sọ ọ́ di ahoro.+ Ó ń dojú rẹ̀ dé,*+ ó sì ń tú àwọn tó ń gbé inú rẹ̀ ká.+
23 Àní, ìparun ráúráú tí Olúwa Ọba Aláṣẹ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun pinnu,Máa ṣẹlẹ̀ ní gbogbo ilẹ̀ náà.+
24 Wò ó! Jèhófà máa sọ ilẹ̀ náà* di òfìfo, ó sì máa sọ ọ́ di ahoro.+ Ó ń dojú rẹ̀ dé,*+ ó sì ń tú àwọn tó ń gbé inú rẹ̀ ká.+