Jeremáyà 15:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Màá kó wọn fún àwọn ọ̀tá rẹKí wọ́n lè kó wọn lọ sí ilẹ̀ tí ìwọ kò mọ̀.+ Torí ìbínú mi ti mú kí iná kan ràn,Á sì máa jó lára rẹ.”+ Sefanáyà 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, nítorí ọjọ́ Jèhófà sún mọ́lé.+ Jèhófà ti pèsè ẹbọ sílẹ̀, ó sì ti ya àwọn tí ó pè sí mímọ́.
14 Màá kó wọn fún àwọn ọ̀tá rẹKí wọ́n lè kó wọn lọ sí ilẹ̀ tí ìwọ kò mọ̀.+ Torí ìbínú mi ti mú kí iná kan ràn,Á sì máa jó lára rẹ.”+
7 Dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, nítorí ọjọ́ Jèhófà sún mọ́lé.+ Jèhófà ti pèsè ẹbọ sílẹ̀, ó sì ti ya àwọn tí ó pè sí mímọ́.