Àìsáyà 47:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àmọ́ nǹkan méjèèjì yìí máa dé bá ọ lójijì, lọ́jọ́ kan ṣoṣo:+ Wàá ṣòfò ọmọ, wàá sì di opó. Wọ́n máa dé bá ọ ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́,+Torí* ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ àjẹ́ rẹ àti gbogbo èèdì rẹ tó lágbára.+ Àìsáyà 48:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Tipẹ́tipẹ́ ni mo ti sọ àwọn ohun àtijọ́* fún ọ. Wọ́n ti ẹnu mi jáde,Mo sì jẹ́ kó di mímọ̀.+ Mo gbé ìgbésẹ̀ lójijì, wọ́n sì ṣẹlẹ̀.+
9 Àmọ́ nǹkan méjèèjì yìí máa dé bá ọ lójijì, lọ́jọ́ kan ṣoṣo:+ Wàá ṣòfò ọmọ, wàá sì di opó. Wọ́n máa dé bá ọ ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́,+Torí* ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ àjẹ́ rẹ àti gbogbo èèdì rẹ tó lágbára.+
3 “Tipẹ́tipẹ́ ni mo ti sọ àwọn ohun àtijọ́* fún ọ. Wọ́n ti ẹnu mi jáde,Mo sì jẹ́ kó di mímọ̀.+ Mo gbé ìgbésẹ̀ lójijì, wọ́n sì ṣẹlẹ̀.+