Jeremáyà 18:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “‘Ṣé mi ò lè ṣe yín bí amọ̀kòkò yìí ti ṣe ni, ẹ̀yin ilé Ísírẹ́lì?’ ni Jèhófà wí. ‘Wò ó! Bí amọ̀ ṣe rí lọ́wọ́ amọ̀kòkò, bẹ́ẹ̀ ni ẹ rí lọ́wọ́ mi, ẹ̀yin ilé Ísírẹ́lì.+
6 “‘Ṣé mi ò lè ṣe yín bí amọ̀kòkò yìí ti ṣe ni, ẹ̀yin ilé Ísírẹ́lì?’ ni Jèhófà wí. ‘Wò ó! Bí amọ̀ ṣe rí lọ́wọ́ amọ̀kòkò, bẹ́ẹ̀ ni ẹ rí lọ́wọ́ mi, ẹ̀yin ilé Ísírẹ́lì.+