Ìsíkíẹ́lì 13:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ṣé ẹ máa sọ mí di aláìmọ́ láàárín àwọn èèyàn mi torí ẹ̀kúnwọ́ ọkà bálì àti èérún búrẹ́dì?+ Ẹ̀ ń pa àwọn* tí kò yẹ kí ẹ pa, ẹ sì ń dá àwọn* tí kò yẹ kí wọ́n wà láàyè sí nípa irọ́ tí ẹ̀ ń pa fún àwọn èèyàn mi, tí àwọn náà sì ń fetí sí i.”’+
19 Ṣé ẹ máa sọ mí di aláìmọ́ láàárín àwọn èèyàn mi torí ẹ̀kúnwọ́ ọkà bálì àti èérún búrẹ́dì?+ Ẹ̀ ń pa àwọn* tí kò yẹ kí ẹ pa, ẹ sì ń dá àwọn* tí kò yẹ kí wọ́n wà láàyè sí nípa irọ́ tí ẹ̀ ń pa fún àwọn èèyàn mi, tí àwọn náà sì ń fetí sí i.”’+