Àìsáyà 45:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,+ Ẹni tó dá a: “Ṣé o máa bi mí nípa àwọn ohun tó ń bọ̀ ni,Kí o sì pàṣẹ fún mi nípa àwọn ọmọ mi+ àti àwọn iṣẹ́ ọwọ́ mi?
11 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,+ Ẹni tó dá a: “Ṣé o máa bi mí nípa àwọn ohun tó ń bọ̀ ni,Kí o sì pàṣẹ fún mi nípa àwọn ọmọ mi+ àti àwọn iṣẹ́ ọwọ́ mi?