Àìsáyà 31:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ó mà ṣe fún àwọn tó ń wá ìrànlọ́wọ́ lọ sọ́dọ̀ Íjíbítì o,+Tí wọ́n gbójú lé ẹṣin,+Tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé kẹ̀kẹ́ ogun, torí pé wọ́n pọ̀,Àti àwọn ẹṣin ogun,* torí pé wọ́n lágbára. Wọn ò yíjú sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,Wọn ò sì wá Jèhófà. Ìsíkíẹ́lì 29:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Gbogbo àwọn tó ń gbé Íjíbítì á wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà,Torí wọn ò lè ti ilé Ísírẹ́lì lẹ́yìn mọ́, wọn ò yàtọ̀ sí pòròpórò* lásán.+
31 Ó mà ṣe fún àwọn tó ń wá ìrànlọ́wọ́ lọ sọ́dọ̀ Íjíbítì o,+Tí wọ́n gbójú lé ẹṣin,+Tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé kẹ̀kẹ́ ogun, torí pé wọ́n pọ̀,Àti àwọn ẹṣin ogun,* torí pé wọ́n lágbára. Wọn ò yíjú sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,Wọn ò sì wá Jèhófà.
6 Gbogbo àwọn tó ń gbé Íjíbítì á wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà,Torí wọn ò lè ti ilé Ísírẹ́lì lẹ́yìn mọ́, wọn ò yàtọ̀ sí pòròpórò* lásán.+