Àìsáyà 51:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ gbọ́ mi, ẹ̀yin èèyàn mi,Kí o sì fetí sí mi, orílẹ̀-èdè mi.+ Torí òfin kan máa jáde látọ̀dọ̀ mi,+Màá sì mú kí ìdájọ́ òdodo mi fìdí múlẹ̀ bí ìmọ́lẹ̀ fún àwọn èèyàn.+
4 Ẹ gbọ́ mi, ẹ̀yin èèyàn mi,Kí o sì fetí sí mi, orílẹ̀-èdè mi.+ Torí òfin kan máa jáde látọ̀dọ̀ mi,+Màá sì mú kí ìdájọ́ òdodo mi fìdí múlẹ̀ bí ìmọ́lẹ̀ fún àwọn èèyàn.+