Mátíù 23:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 “Jerúsálẹ́mù, Jerúsálẹ́mù, ìlú tó ń pa àwọn wòlíì, tó sì ń sọ àwọn tí a rán sí i lókùúta,+ wo bí mo ṣe máa ń fẹ́ kó àwọn ọmọ rẹ jọ tó lọ́pọ̀ ìgbà, bí ìgbà tí adìyẹ ń kó àwọn ọmọ rẹ̀ jọ sábẹ́ ìyẹ́ rẹ̀! Àmọ́ ẹ ò fẹ́ bẹ́ẹ̀.+ Ìṣe 7:51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 “Ẹ̀yin olóríkunkun àti aláìkọlà* ọkàn àti etí, gbogbo ìgbà lẹ̀ ń ta ko ẹ̀mí mímọ́; bí àwọn baba ńlá yín ti ṣe náà lẹ̀ ń ṣe.+
37 “Jerúsálẹ́mù, Jerúsálẹ́mù, ìlú tó ń pa àwọn wòlíì, tó sì ń sọ àwọn tí a rán sí i lókùúta,+ wo bí mo ṣe máa ń fẹ́ kó àwọn ọmọ rẹ jọ tó lọ́pọ̀ ìgbà, bí ìgbà tí adìyẹ ń kó àwọn ọmọ rẹ̀ jọ sábẹ́ ìyẹ́ rẹ̀! Àmọ́ ẹ ò fẹ́ bẹ́ẹ̀.+
51 “Ẹ̀yin olóríkunkun àti aláìkọlà* ọkàn àti etí, gbogbo ìgbà lẹ̀ ń ta ko ẹ̀mí mímọ́; bí àwọn baba ńlá yín ti ṣe náà lẹ̀ ń ṣe.+