-
Ìsíkíẹ́lì 12:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Àmọ́ màá gba díẹ̀ lára wọn lọ́wọ́ idà, ìyàn àti àjàkálẹ̀ àrùn, kí wọ́n lè ròyìn gbogbo ohun tó ń ríni lára tí wọ́n ṣe láàárín àwọn orílẹ̀-èdè tí wọn yóò lọ; wọ́n á sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.”
-