- 
	                        
            
            Àìsáyà 61:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        3 Láti pèsè fún àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ torí Síónì, Láti fún wọn ní ìwérí dípò eérú, Òróró ayọ̀ dípò ọ̀fọ̀, Aṣọ ìyìn dípò ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn. 
 
- 
                                        
3 Láti pèsè fún àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ torí Síónì,
Láti fún wọn ní ìwérí dípò eérú,
Òróró ayọ̀ dípò ọ̀fọ̀,
Aṣọ ìyìn dípò ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn.