Àìsáyà 60:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Oòrùn rẹ ò ní wọ̀ mọ́,Òṣùpá rẹ ò sì ní wọ̀ọ̀kùn,Torí pé Jèhófà máa di ìmọ́lẹ̀ ayérayé fún ọ,+Àwọn ọjọ́ ọ̀fọ̀ rẹ sì máa dópin.+ Ìfihàn 21:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ìlú náà ò nílò kí oòrùn tàbí òṣùpá tàn sórí rẹ̀, torí ògo Ọlọ́run mú kó mọ́lẹ̀ rekete,+ Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà sì ni fìtílà rẹ̀.+ Ìfihàn 22:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bákan náà, ilẹ̀ ò ní ṣú mọ́,+ wọn ò sì nílò ìmọ́lẹ̀ fìtílà tàbí ìmọ́lẹ̀ oòrùn, torí pé Jèhófà* Ọlọ́run máa tan ìmọ́lẹ̀ sórí wọn,+ wọ́n sì máa jọba títí láé àti láéláé.+
20 Oòrùn rẹ ò ní wọ̀ mọ́,Òṣùpá rẹ ò sì ní wọ̀ọ̀kùn,Torí pé Jèhófà máa di ìmọ́lẹ̀ ayérayé fún ọ,+Àwọn ọjọ́ ọ̀fọ̀ rẹ sì máa dópin.+
23 Ìlú náà ò nílò kí oòrùn tàbí òṣùpá tàn sórí rẹ̀, torí ògo Ọlọ́run mú kó mọ́lẹ̀ rekete,+ Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà sì ni fìtílà rẹ̀.+
5 Bákan náà, ilẹ̀ ò ní ṣú mọ́,+ wọn ò sì nílò ìmọ́lẹ̀ fìtílà tàbí ìmọ́lẹ̀ oòrùn, torí pé Jèhófà* Ọlọ́run máa tan ìmọ́lẹ̀ sórí wọn,+ wọ́n sì máa jọba títí láé àti láéláé.+