Ìdárò 2:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kí ni màá fi ṣe ẹ̀rí,Àbí kí ni màá fi ọ́ wé, ìwọ ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù? Kí ni màá fi ọ́ wé, kí n lè tù ọ́ nínú, ìwọ wúńdíá ọmọbìnrin Síónì? Nítorí ọgbẹ́ rẹ pọ̀ gan-an, ó fẹ̀ bí omi òkun.+ Ta ló lè wò ọ́ sàn?+
13 Kí ni màá fi ṣe ẹ̀rí,Àbí kí ni màá fi ọ́ wé, ìwọ ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù? Kí ni màá fi ọ́ wé, kí n lè tù ọ́ nínú, ìwọ wúńdíá ọmọbìnrin Síónì? Nítorí ọgbẹ́ rẹ pọ̀ gan-an, ó fẹ̀ bí omi òkun.+ Ta ló lè wò ọ́ sàn?+