Àìsáyà 10:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Tí Jèhófà bá ti parí gbogbo iṣẹ́ rẹ̀ lórí Òkè Síónì àti ní Jerúsálẹ́mù, Ó* máa fìyà jẹ ọba Ásíríà torí àfojúdi ọkàn rẹ̀ àti ojú rẹ̀ gíga tó fi ń woni pẹ̀lú ìgbéraga.+
12 “Tí Jèhófà bá ti parí gbogbo iṣẹ́ rẹ̀ lórí Òkè Síónì àti ní Jerúsálẹ́mù, Ó* máa fìyà jẹ ọba Ásíríà torí àfojúdi ọkàn rẹ̀ àti ojú rẹ̀ gíga tó fi ń woni pẹ̀lú ìgbéraga.+