-
Sáàmù 46:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Àwọn orílẹ̀-èdè wà nínú rúkèrúdò, àwọn ìjọba ń ṣubú;
Ó gbé ohùn rẹ̀ sókè, ayé sì yọ́.+
-
-
Sáàmù 68:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
68 Kí Ọlọ́run dìde, kí àwọn ọ̀tá rẹ̀ tú ká,
Kí àwọn tó kórìíra rẹ̀ sì sá kúrò níwájú rẹ̀.+
-
-
Àìsáyà 17:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ìró àwọn orílẹ̀-èdè máa dà bí ariwo omi púpọ̀.
-