Òwe 19:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ìbẹ̀rù Jèhófà ń yọrí sí ìyè;+Ẹni tó bá ní in yóò sun oorun àsùnwọra, láìsí aburú kankan.+