-
Àìsáyà 9:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Torí pé ìwà burúkú máa ń jó bí iná,
Ó ń jó àwọn igi ẹlẹ́gùn-ún àti èpò run.
Ó máa dáná sí igbó tó díjú,
Èéfín wọn tó ṣú sì máa ròkè lálá.
-