-
Ìsíkíẹ́lì 18:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 kì í ni àwọn aláìní lára; kì í gba èlé gọbọi lórí owó tó yáni, kì í sì í yáni lówó èlé; ó ń tẹ̀ lé ìdájọ́ mi; ó sì ń pa àwọn àṣẹ mi mọ́. Irú ẹni bẹ́ẹ̀ kò ní kú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ bàbá rẹ̀. Ó dájú pé yóò máa wà láàyè.
-