2 Àwọn Ọba 15:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Púlì+ ọba Ásíríà wá sí ilẹ̀ náà, Ménáhémù sì fún Púlì ní ẹgbẹ̀rún kan (1,000) tálẹ́ńtì* fàdákà nítorí ó tì í lẹ́yìn kí ìjọba má bàa bọ́ mọ́ ọn lọ́wọ́.+
19 Púlì+ ọba Ásíríà wá sí ilẹ̀ náà, Ménáhémù sì fún Púlì ní ẹgbẹ̀rún kan (1,000) tálẹ́ńtì* fàdákà nítorí ó tì í lẹ́yìn kí ìjọba má bàa bọ́ mọ́ ọn lọ́wọ́.+