-
Hósíà 14:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Màá máa sẹ̀ bí ìrì sórí Ísírẹ́lì;
Á yọ ìtànná bí òdòdó lílì
Á sì ta gbòǹgbò rẹ̀ bí àwọn igi Lẹ́bánónì.
6 Àwọn ẹ̀ka rẹ̀ á tẹ́ rẹrẹ,
Ògo rẹ̀ á dà bíi ti igi ólífì,
Ìtasánsán rẹ̀ á sì dà bíi ti Lẹ́bánónì.
-