2 Kíróníkà 32:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Lẹ́yìn náà, nígbà tí Senakérúbù ọba Ásíríà wà ní Lákíṣì+ pẹ̀lú gbogbo ogun rẹ̀,* ó rán àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ sí Jerúsálẹ́mù, sí Hẹsikáyà ọba Júdà àti sí gbogbo àwọn ará Jùdíà tó wà ní Jerúsálẹ́mù,+ ó sọ pé:
9 Lẹ́yìn náà, nígbà tí Senakérúbù ọba Ásíríà wà ní Lákíṣì+ pẹ̀lú gbogbo ogun rẹ̀,* ó rán àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ sí Jerúsálẹ́mù, sí Hẹsikáyà ọba Júdà àti sí gbogbo àwọn ará Jùdíà tó wà ní Jerúsálẹ́mù,+ ó sọ pé: