Àìsáyà 22:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ohun tí Olúwa Ọba Aláṣẹ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, sọ nìyí: “Wọlé lọ bá ìríjú yìí, ìyẹn Ṣébínà,+ ẹni tó ń bójú tó ilé,* kí o sì sọ fún un pé,
15 Ohun tí Olúwa Ọba Aláṣẹ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, sọ nìyí: “Wọlé lọ bá ìríjú yìí, ìyẹn Ṣébínà,+ ẹni tó ń bójú tó ilé,* kí o sì sọ fún un pé,