-
2 Kíróníkà 32:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Wọ́n gbóhùn sókè, wọ́n ń sọ̀rọ̀ ní èdè àwọn Júù sí àwọn èèyàn Jerúsálẹ́mù tó wà lórí ògiri, láti dẹ́rù bà wọ́n kí wọ́n sì kó jìnnìjìnnì bá wọn, kí wọ́n lè gba ìlú náà.+
-