ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 32:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ṣé ẹ ò mọ̀ pé Hẹsikáyà ń ṣì yín lọ́nà ni, tó fẹ́ kí ìyàn àti òùngbẹ pa yín kú, bó ṣe ń sọ pé: “Jèhófà Ọlọ́run wa yóò gbà wá lọ́wọ́ ọba Ásíríà”?+

  • 2 Kíróníkà 32:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Torí náà, ẹ má ṣe jẹ́ kí Hẹsikáyà fi èyí tàn yín jẹ tàbí kó ṣì yín lọ́nà!+ Ẹ má gbà á gbọ́, nítorí kò sí ọlọ́run orílẹ̀-èdè kankan tàbí ìjọba èyíkéyìí tó gba àwọn èèyàn rẹ̀ lọ́wọ́ mi àti lọ́wọ́ àwọn baba ńlá mi. Ká má ṣẹ̀ṣẹ̀ wá sọ ti Ọlọ́run yín pé á gbà yín lọ́wọ́ mi!’”+

  • Dáníẹ́lì 3:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ní báyìí, tí ẹ bá gbọ́ ìró ìwo, fèrè ape, ọpọ́n orin olókùn púpọ̀, háàpù onígun mẹ́ta, ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín, fèrè alápò awọ àti gbogbo ohun ìkọrin míì, ohun tó máa dáa ni pé kí ẹ ṣe tán láti wólẹ̀, kí ẹ sì jọ́sìn ère tí mo ṣe. Àmọ́ tí ẹ bá kọ̀ láti jọ́sìn, ẹsẹ̀kẹsẹ̀ ni wọ́n máa jù yín sínú iná ìléru tó ń jó. Ta sì ni ọlọ́run tó lè gbà yín sílẹ̀ lọ́wọ́ mi?”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́