2 Àwọn Ọba 19:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ta lo pẹ̀gàn, tí o sì sọ̀rọ̀ òdì sí?+ Ta lo gbé ohùn rẹ sókè sí,+Tí o sì gbé ojú rẹ ga sí? Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì mà ni!+
22 Ta lo pẹ̀gàn, tí o sì sọ̀rọ̀ òdì sí?+ Ta lo gbé ohùn rẹ sókè sí,+Tí o sì gbé ojú rẹ ga sí? Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì mà ni!+