Àìsáyà 26:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Bí aláboyún tó fẹ́ bímọ,Tó ń rọbí, tó sì ń ké torí ó ń jẹ̀rora,Bẹ́ẹ̀ ni a ṣe rí nítorí rẹ, Jèhófà. 18 A lóyún, a sì ní ìrora ìrọbí,Àmọ́ ṣe ló dà bíi pé afẹ́fẹ́ la bí. A ò mú ìgbàlà wá sí ilẹ̀ náà,A ò sì bí ẹnì kankan tó máa gbé ilẹ̀ náà.
17 Bí aláboyún tó fẹ́ bímọ,Tó ń rọbí, tó sì ń ké torí ó ń jẹ̀rora,Bẹ́ẹ̀ ni a ṣe rí nítorí rẹ, Jèhófà. 18 A lóyún, a sì ní ìrora ìrọbí,Àmọ́ ṣe ló dà bíi pé afẹ́fẹ́ la bí. A ò mú ìgbàlà wá sí ilẹ̀ náà,A ò sì bí ẹnì kankan tó máa gbé ilẹ̀ náà.