ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 8:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Kí o gbọ́ ẹ̀bẹ̀ ìránṣẹ́ rẹ fún ojú rere àti ẹ̀bẹ̀ àwọn èèyàn rẹ Ísírẹ́lì, tí wọ́n ń sọ nínú àdúrà ní ìdojúkọ ibí yìí; kí o gbọ́ láti ibi tí ò ń gbé ní ọ̀run;+ kí o gbọ́, kí o sì dárí jì wọ́n.+

  • 2 Kíróníkà 6:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Kí ojú rẹ wà lára ilé yìí tọ̀sántòru, lára ibi tí o sọ pé wàá fi orúkọ rẹ sí,+ láti fetí sí àdúrà tí ìránṣẹ́ rẹ ń gbà ní ìdojúkọ ibí yìí.

  • 2 Kíróníkà 20:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 ‘Tí àjálù bá dé bá wa, ì báà jẹ́ idà tàbí ìdájọ́ tí kò bára dé tàbí àjàkálẹ̀ àrùn tàbí ìyàn, jẹ́ ká dúró níwájú ilé yìí àti níwájú rẹ (nítorí orúkọ rẹ wà nínú ilé yìí),+ ká sì ké pè ọ́ pé kí o ràn wá lọ́wọ́ nínú wàhálà wa, kí o gbọ́ kí o sì gbà wá.’+

  • Dáníẹ́lì 9:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Mo wá yíjú sí Jèhófà Ọlọ́run tòótọ́, mo bẹ̀ ẹ́ bí mo ṣe ń gbàdúrà sí i, pẹ̀lú ààwẹ̀,+ aṣọ ọ̀fọ̀* àti eérú.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́