Sáàmù 46:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wà pẹ̀lú wa;+Ọlọ́run Jékọ́bù ni ibi ààbò wa.* (Sélà) Àìsáyà 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni Ẹni tó yẹ kí ẹ kà sí mímọ́,+Òun ni Ẹni tó yẹ kí ẹ bẹ̀rù,Òun sì ni Ẹni tó yẹ kó mú kí ẹ gbọ̀n jìnnìjìnnì.”+
13 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni Ẹni tó yẹ kí ẹ kà sí mímọ́,+Òun ni Ẹni tó yẹ kí ẹ bẹ̀rù,Òun sì ni Ẹni tó yẹ kó mú kí ẹ gbọ̀n jìnnìjìnnì.”+