Àìsáyà 10:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọwọ́ mi tẹ ìjọba àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí,Àwọn tí ère gbígbẹ́ wọn pọ̀ ju ti Jerúsálẹ́mù àti Samáríà lọ!+ 11 Ǹjẹ́ kì í ṣe ohun tí mo ṣe sí Samáríà àti àwọn ọlọ́run rẹ̀ tí kò ní láárí gẹ́lẹ́Ni màá ṣe sí Jerúsálẹ́mù àti àwọn òrìṣà rẹ̀?’+
10 Ọwọ́ mi tẹ ìjọba àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí,Àwọn tí ère gbígbẹ́ wọn pọ̀ ju ti Jerúsálẹ́mù àti Samáríà lọ!+ 11 Ǹjẹ́ kì í ṣe ohun tí mo ṣe sí Samáríà àti àwọn ọlọ́run rẹ̀ tí kò ní láárí gẹ́lẹ́Ni màá ṣe sí Jerúsálẹ́mù àti àwọn òrìṣà rẹ̀?’+