ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 46:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Àwọn orílẹ̀-èdè wà nínú rúkèrúdò, àwọn ìjọba ń ṣubú;

      Ó gbé ohùn rẹ̀ sókè, ayé sì yọ́.+

  • Àìsáyà 10:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ṣé àáké máa gbé ara rẹ̀ ga ju ẹni tó ń fi gé nǹkan?

      Ṣé ayùn máa gbé ara rẹ̀ ga ju ẹni tó ń fi rẹ́ nǹkan?

      Ṣé ọ̀pá+ lè fi ẹni tó gbé e sókè?

      Àbí ọ̀pá lè gbé ẹni tí wọn ò fi igi ṣe sókè?

  • Àìsáyà 37:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Ta lo pẹ̀gàn,+ tí o sì sọ̀rọ̀ òdì sí?

      Ta lo gbé ohùn rẹ sókè sí,+

      Tí o sì gbé ojú rẹ ga sí?

      Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì mà ni!+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́