2 Àwọn Ọba 19:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Bóyá Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa gbọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ Rábúṣákè tí olúwa rẹ̀ ọba Ásíríà rán láti pẹ̀gàn Ọlọ́run alààyè,+ tí á sì pè é wá jíhìn nítorí àwọn ọ̀rọ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti gbọ́. Torí náà, gbàdúrà nítorí àṣẹ́kù+ tó yè bọ́ yìí.’”
4 Bóyá Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa gbọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ Rábúṣákè tí olúwa rẹ̀ ọba Ásíríà rán láti pẹ̀gàn Ọlọ́run alààyè,+ tí á sì pè é wá jíhìn nítorí àwọn ọ̀rọ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti gbọ́. Torí náà, gbàdúrà nítorí àṣẹ́kù+ tó yè bọ́ yìí.’”