2 Àwọn Ọba 19:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wò ó, màá fi ohun kan sí i lọ́kàn,* ó máa gbọ́ ìròyìn kan, á sì pa dà sí ilẹ̀ rẹ̀; màá sì jẹ́ kí wọ́n fi idà pa á ní ilẹ̀ òun fúnra rẹ̀.”’”+ 2 Àwọn Ọba 19:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Torí bí inú rẹ ṣe ń ru sí mi+ àti bí o ṣe ń ké ramúramù ti dé etí mi.+ Torí náà, màá fi ìwọ̀ mi kọ́ imú rẹ,+ màá fi ìjánu mi sáàárín ètè rẹ,Ọ̀nà tí o gbà wá ni màá sì mú ọ gbà pa dà.”+
7 Wò ó, màá fi ohun kan sí i lọ́kàn,* ó máa gbọ́ ìròyìn kan, á sì pa dà sí ilẹ̀ rẹ̀; màá sì jẹ́ kí wọ́n fi idà pa á ní ilẹ̀ òun fúnra rẹ̀.”’”+
28 Torí bí inú rẹ ṣe ń ru sí mi+ àti bí o ṣe ń ké ramúramù ti dé etí mi.+ Torí náà, màá fi ìwọ̀ mi kọ́ imú rẹ,+ màá fi ìjánu mi sáàárín ètè rẹ,Ọ̀nà tí o gbà wá ni màá sì mú ọ gbà pa dà.”+