Oníwàásù 8:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹlẹ́ṣẹ̀ lè ṣe búburú ní ọgọ́rùn-ún ìgbà, kó sì pẹ́ láyé, síbẹ̀ mo mọ̀ pé ó máa dára fún àwọn tó bẹ̀rù Ọlọ́run tòótọ́, nítorí wọ́n bẹ̀rù rẹ̀.+ Sefanáyà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ wá Jèhófà,+ gbogbo ẹ̀yin oníwà pẹ̀lẹ́* ayé,Tó ń pa àṣẹ òdodo* rẹ̀ mọ́. Ẹ wá òdodo, ẹ wá ìwà pẹ̀lẹ́.* Bóyá* ẹ ó rí ààbò ní ọjọ́ ìbínú Jèhófà.+
12 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹlẹ́ṣẹ̀ lè ṣe búburú ní ọgọ́rùn-ún ìgbà, kó sì pẹ́ láyé, síbẹ̀ mo mọ̀ pé ó máa dára fún àwọn tó bẹ̀rù Ọlọ́run tòótọ́, nítorí wọ́n bẹ̀rù rẹ̀.+
3 Ẹ wá Jèhófà,+ gbogbo ẹ̀yin oníwà pẹ̀lẹ́* ayé,Tó ń pa àṣẹ òdodo* rẹ̀ mọ́. Ẹ wá òdodo, ẹ wá ìwà pẹ̀lẹ́.* Bóyá* ẹ ó rí ààbò ní ọjọ́ ìbínú Jèhófà.+