2 Àwọn Ọba 19:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àìsáyà ọmọ Émọ́ọ̀sì wá ránṣẹ́ sí Hẹsikáyà pé: “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ‘Mo ti gbọ́ àdúrà tí o gbà+ sí mi nítorí Senakérúbù ọba Ásíríà.+ Àìsáyà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ìran tí Àìsáyà*+ ọmọ Émọ́ọ̀sì rí nípa Júdà àti Jerúsálẹ́mù láyé ìgbà Ùsáyà,+ Jótámù,+ Áhásì+ àti Hẹsikáyà,+ àwọn ọba Júdà:+
20 Àìsáyà ọmọ Émọ́ọ̀sì wá ránṣẹ́ sí Hẹsikáyà pé: “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ‘Mo ti gbọ́ àdúrà tí o gbà+ sí mi nítorí Senakérúbù ọba Ásíríà.+
1 Ìran tí Àìsáyà*+ ọmọ Émọ́ọ̀sì rí nípa Júdà àti Jerúsálẹ́mù láyé ìgbà Ùsáyà,+ Jótámù,+ Áhásì+ àti Hẹsikáyà,+ àwọn ọba Júdà:+