Òwe 15:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Jèhófà jìnnà réré sí àwọn ẹni burúkú,Àmọ́ ó máa ń gbọ́ àdúrà àwọn olódodo.+ 1 Jòhánù 5:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ohun tó dá wa lójú nípa rẹ̀ ni pé,*+ tí a bá béèrè ohunkóhun tó bá ìfẹ́ rẹ̀ mu, ó ń gbọ́ wa.+