- 
	                        
            
            2 Kíróníkà 32:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        22 Bí Jèhófà ṣe gba Hẹsikáyà àti àwọn tó ń gbé Jerúsálẹ́mù lọ́wọ́ Senakérúbù ọba Ásíríà nìyẹn àti lọ́wọ́ gbogbo àwọn yòókù, ó sì fún wọn ní ìsinmi kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá tó yí wọn ká. 
 
-