Sáàmù 146:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ̀mí* rẹ̀ jáde lọ, ó pa dà sínú ilẹ̀;+Ọjọ́ yẹn gan-an ni èrò inú rẹ̀ ṣègbé.+ Oníwàásù 8:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Bí kò ṣe sí èèyàn tó lágbára lórí ẹ̀mí* tàbí tó lè dá ẹ̀mí dúró, bẹ́ẹ̀ ni kò sẹ́ni tó lágbára lórí ọjọ́ ikú.+ Bí ẹnikẹ́ni kò ṣe lè dá ara rẹ̀ sílẹ̀ lójú ogun, bẹ́ẹ̀ ni ìwà burúkú kò ní jẹ́ kí àwọn tó ń hù ú yè bọ́.*
8 Bí kò ṣe sí èèyàn tó lágbára lórí ẹ̀mí* tàbí tó lè dá ẹ̀mí dúró, bẹ́ẹ̀ ni kò sẹ́ni tó lágbára lórí ọjọ́ ikú.+ Bí ẹnikẹ́ni kò ṣe lè dá ara rẹ̀ sílẹ̀ lójú ogun, bẹ́ẹ̀ ni ìwà burúkú kò ní jẹ́ kí àwọn tó ń hù ú yè bọ́.*