- 
	                        
            
            Àìsáyà 59:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        11 Gbogbo wa ń kùn ṣáá bíi bíárì, A sì ń ṣọ̀fọ̀, à ń ké kúùkúù bí àdàbà. À ń retí ìdájọ́ òdodo, àmọ́ kò sí; À ń retí ìgbàlà, àmọ́ ó jìnnà gan-an sí wa. 
 
-