Sáàmù 30:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Èrè wo ló wà nínú ikú* mi, nínú bí mo ṣe ń lọ sínú kòtò?*+ Ṣé erùpẹ̀ lè yìn ọ́?+ Ṣé ó lè sọ nípa ìṣòtítọ́ rẹ?+
9 Èrè wo ló wà nínú ikú* mi, nínú bí mo ṣe ń lọ sínú kòtò?*+ Ṣé erùpẹ̀ lè yìn ọ́?+ Ṣé ó lè sọ nípa ìṣòtítọ́ rẹ?+