Sáàmù 6:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí òkú kò lè sọ nípa* rẹ;Àbí, ta ló lè yìn ọ́ nínú Isà Òkú?*+ Sáàmù 115:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àwọn òkú kì í yin Jáà;+Bẹ́ẹ̀ ni ẹnikẹ́ni tó sọ̀ kalẹ̀ lọ sínú ìdákẹ́jẹ́ẹ́ ikú.*+