2 Àwọn Ọba 20:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àìsáyà wá sọ pé: “Ẹ mú ìṣù ọ̀pọ̀tọ́ gbígbẹ wá.” Nítorí náà, wọ́n mú un wá, wọ́n sì fi í sí eéwo náà, ní kẹ̀rẹ̀kẹ̀rẹ̀, ara rẹ̀ yá.+
7 Àìsáyà wá sọ pé: “Ẹ mú ìṣù ọ̀pọ̀tọ́ gbígbẹ wá.” Nítorí náà, wọ́n mú un wá, wọ́n sì fi í sí eéwo náà, ní kẹ̀rẹ̀kẹ̀rẹ̀, ara rẹ̀ yá.+