2 Kíróníkà 32:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ọ̀pọ̀ èèyàn mú ẹ̀bùn wá fún Jèhófà ní Jerúsálẹ́mù, wọ́n sì mú àwọn ohun iyebíye wá fún Hẹsikáyà ọba Júdà,+ gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè sì ń bọ̀wọ̀ fún un gidigidi lẹ́yìn náà.
23 Ọ̀pọ̀ èèyàn mú ẹ̀bùn wá fún Jèhófà ní Jerúsálẹ́mù, wọ́n sì mú àwọn ohun iyebíye wá fún Hẹsikáyà ọba Júdà,+ gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè sì ń bọ̀wọ̀ fún un gidigidi lẹ́yìn náà.