2 Àwọn Ọba 20:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ni Hẹsikáyà bá sọ fún Àìsáyà pé: “Ọ̀rọ̀ Jèhófà tí o sọ dára.”+ Ó wá fi kún un pé: “Tí àlàáfíà àti ìfọkànbalẹ̀* bá ti wà lásìkò* mi,+ ó ti dáa.”
19 Ni Hẹsikáyà bá sọ fún Àìsáyà pé: “Ọ̀rọ̀ Jèhófà tí o sọ dára.”+ Ó wá fi kún un pé: “Tí àlàáfíà àti ìfọkànbalẹ̀* bá ti wà lásìkò* mi,+ ó ti dáa.”