Àìsáyà 12:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+ Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+ Àìsáyà 25:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n máa sọ pé: “Wò ó! Ọlọ́run wa nìyí!+ A ti gbẹ́kẹ̀ lé e,+Ó sì máa gbà wá là.+ Jèhófà nìyí! A ti gbẹ́kẹ̀ lé e. Ẹ jẹ́ ká máa yọ̀, kí inú wa sì dùn torí ìgbàlà rẹ̀.”+
2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+ Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+
9 Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n máa sọ pé: “Wò ó! Ọlọ́run wa nìyí!+ A ti gbẹ́kẹ̀ lé e,+Ó sì máa gbà wá là.+ Jèhófà nìyí! A ti gbẹ́kẹ̀ lé e. Ẹ jẹ́ ká máa yọ̀, kí inú wa sì dùn torí ìgbàlà rẹ̀.”+