-
Jẹ́nẹ́sísì 33:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Àmọ́ ó sọ fún un pé: “Olúwa mi mọ̀ pé àwọn ọmọ ò fi bẹ́ẹ̀ lágbára,+ mo sì ní àwọn àgùntàn àti màlúù tó ń tọ́mọ lọ́wọ́. Tí mo bá yára dà wọ́n jù láàárín ọjọ́ kan, gbogbo ẹran ló máa kú.
-