-
Jeremáyà 4:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 “Bí o bá máa pa dà, ìwọ Ísírẹ́lì,” ni Jèhófà wí,
“Bí o bá máa pa dà sọ́dọ̀ mi
Kí o mú òrìṣà ẹ̀gbin rẹ kúrò níwájú mi,
Nígbà náà, ìwọ kò ní jẹ́ ìsáǹsá.+
-
-
Hósíà 14:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “Pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run rẹ, ìwọ Ísírẹ́lì,+
Torí àṣìṣe rẹ ti mú kí o kọsẹ̀.
-